Wise Message lyric by Alfa Olooye Agbaye
Wise Message lyric Written by Alfa Olooye Agbaye Chorus Igbiyanju ni ladder, ten yan fi di leader, lailai si ladder yen ko easy kadolori Igbiyanju, Igbiyanju ….. Igbiyanju, Igbiyanju….. Igbiyanju ooo, Igbiyanju ……… Igbiyanju ni ladder, ten yan fi di leader, lailai si ladder yen ko easy kadolorii Chorus… Alfa Olooye Ayinla nanwii, Alfa Olooye Agbaye nan wii, okunrin ogun, olori sha ni leader, ekolo n shebi ejo, aba niwon nda, koda bi e nidan lowo bi America wonder, toga yin bade se lema surrender, akeide salawa awa di commander, ameer orinju orin lo ariwo koni music, wonni awon pe nbe abawon ajuwon le, kinni oje kayato, nigba tao ko nonsense, toripe hadith anobi oun pelu Qurani, oro ologbon lanlo awon sani reference, tabawa she bayii, ara lanfinda, Imuse producer, TOSBLES jekanmo,…………….. kawon oloo un adidun yen dunhun si koriwu. Chorus… Baye shenlo madabi omi adagun, lofa New dimension otun lotun lorin wa, "Ina mina shinri laa hikmo", ogbon wa ninu orin iyen toba list...