Wise Message lyric by Alfa Olooye Agbaye


 Wise Message lyric

Written by Alfa Olooye Agbaye


Chorus

Igbiyanju ni ladder, ten yan fi di leader, lailai si ladder yen ko easy kadolori


Igbiyanju, Igbiyanju ….. Igbiyanju, Igbiyanju….. Igbiyanju ooo, Igbiyanju ……… Igbiyanju ni ladder, ten yan fi di leader, lailai si ladder yen ko easy kadolorii

Chorus…


Alfa Olooye Ayinla nanwii, Alfa Olooye Agbaye nan wii, okunrin ogun, olori sha ni leader, ekolo n shebi ejo, aba niwon nda, koda bi e nidan lowo bi America wonder, toga yin bade se lema surrender, akeide salawa awa di commander, ameer orinju orin lo ariwo koni music, wonni awon pe nbe abawon ajuwon le, kinni oje kayato, nigba tao ko nonsense, toripe hadith anobi oun pelu Qurani, oro ologbon lanlo awon sani reference, tabawa she bayii, ara lanfinda, Imuse producer, TOSBLES jekanmo,…………….. kawon oloo un adidun yen dunhun si koriwu.

Chorus…

Baye shenlo madabi omi adagun, lofa New dimension otun lotun lorin wa, "Ina mina shinri laa hikmo", ogbon wa ninu orin iyen toba listen, ninu to dun pass message ju laye, okan shaa lorin topi opo eyan loferan music, oun toba so nibe loma je message, toba wa ko nonsense ajepe orin yen owa useful, kokan wa pelu ilu tabi bose koosi, toro inu e bawulo, oun loko orin ologbo, wasi sale yin, wasi saleyin fun olorin ijo lasan,

Chorus…

Ore wa olo n sun lasiko hustle, oya ji masun, aponle osi fun tree igi tio lewe lori, koleso lori, okan ma wa useless igba yen owulo, tio bale bu water, nkan ase eni tio se nkan, ko keu, kolo school, koni se lowo, kinni ofe future, ojo nlo koduro, Al waqtu ka zeifi, inlam taktohu, kotoaka, asiko dabi sword tobafi genkan, ere lofin se oma gee nigbeyin, igbiyanju ni koko, fil araka, Al Baraka, ninu igbiyanju o lanu olohun magbe.

Chorus…

Enu kinnihun lowo wa, amo ko easy, dandan ni ki eda o ni, laye yi owo lo matter , eni oo lowo lowo, won so pe koni level, Maolana sheikh Adam, Al- ilori baba lagege jawa tan, .....

"Ayatun bila moolin, ayatun musilatun kalamu bila jaiin kalamu mudoyahu, wain kunta sa moolin, faa anta muhababun, wakooluka moqbulun, wahukmuka yutihun", aye nse tuale, seni kan bee lapo, bio basi money, kole soro kaaye o gbo, olowo lay emo, owo ni koko.

Chorus…

Anobi Muhammod, solallahu alehi, qoola, "Al- yadul ulya, kherun, mina l yadi sufila", owo toje upper osan ju ti lower, maya alatoroje, gbinyaju kole fun yan, aye yi o easy, sugbon mamu yen ni reason, kun fun adura ni o, koma bee olohun oba,  odamiloju oo, odamiloju o oma dolola,

Chorus…


Abdul Somodi oo Alfa Olooye


Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

Next Dimension lyric by Alfa Olooye Agbaye